Oniwaasu ATI ADURA
Priez sans cesse
16/08/2022
Ibunkun ni fun awon tio pé ni onan nan tio si rin tunutunu rè gbogbo , iwo ayonfè iwo ni Oro yi bawi lati jéwo wipé Jésu ni onan otito ATI ododo , ki OSI Dara fun ô Amin
23/06/2022
Bibeli so wipe anu ni mofè ki sé èbô : toba ri bè olorun fi anu wa wa ri ki wa kio lemo pe iwo ni oluwa kosi elomiran
06/06/2022
Adura, ORIN Davidi 121: émi yoo gbé oju mi si Ori oke won ni ,nibo ni iranlowo mi yoo ti wa , iranlowo yoo ti ôwô oluwa wa tio ôrun houn ayé
29/05/2022
ORIN Davidi ORI 27: oluwa ni imolè mi ATI igbala mi ,ta ni émi o bèru ? oluwa ni agbara émi mi, Aya ni yoo fo mi nigba ti awon eniyan buburu,Ani awon ôta mi ATI awon abinuku mi sunmo mi lati je éran ara mi won kose ,won si subu, adura mi si ô ni pé gbogbo alagbara to baôja loju ala ki gbogbo won segbé niwaju rè
Gloire de DIEU
24/05/2022
Ni atetekose ni Orô wa , Orô si wa pèlu olorun, olorun si ni Orô na , nitori nan Orô wa sôrarè jade ami
Cliquez ici pour réclamer votre Listage Commercial.
Téléphone
Site Web
Adresse
Cotonou
