Voice of God backup
To support this great commission. +2349161771064
I’m an Evangelist Kingdom preacher with a mandate for Revival, teaching the undiluted word of God through radio,TV, books, and other media to depopulate the satanic kingdom and populate the Kingdom of God.
Eleyi fun oo ni ose yi.
23/06/2026
Ẹgbọ ẹyin eniyan, ileṣẹ Radio wo niyi ti Seyi Makinde lọba wọn si nigba kan? Ti ẹba mọ ẹ darukọ rẹ ati orukọ ẹniti oni?
23/06/2026
Gbogbo ẹyin Muslim ẹlẹkẹ ebu to n bumi, Darukọ eniyan gidi bi temi kan fun mi ninu islam yin,
toni orukọ rere tose fikọ eniyan lẹkọ lawujọ wa loni, ati ni agbole yin gan pẹlu, Toni ẹkọ rere Ọlọrun,
Tikise ẹkọ Allah sigidi mujẹmijẹ ọlọwọ ọtun meji tise orisha Saudi,
Ti ẹ n kirun wakati marun fun lojojumọ, Nitori alujanna, sugbọ tojẹ ina lopada selori rẹ fun yin, lati koyin lọ Quran 19.71-72.
Tabi ki ẹsọ fun mi, orukọ rere ti ọbaye jẹ eniyan ti ẹ n pe ni Muhammad yin ni, tose fikọ awọn ọmọ lẹkọ lawujọ wa loni, tofi jumi lọ, tabi tofi daraju mi lọ?
Iwọ ti obafẹ pari irinajo rẹ sinu Ina, mafi aye rẹ fun JESU, odi ọjọ ti obadiju saye, ti osi ba ara rẹ ninu ina, ki o tomọ wipe,
JESU NI OLUGBALA NA TI ỌLỌRUN RAN SI ARA YE John 3.16-21, Ifihan 22.12-16, Ise Apostle 4.12-13, Quran 4 vs 159.
22/06/2026
Ẹgbọ Ninu awa ọmọ lẹyin Kristi, pẹlu awon oni ṣẹṣe, ati awon muslim ọmọ lẹyin Muhammad,
awọn wo loma n ṣẹ egbe ninu wọn? tabi to ma n fi egbe daun ibere ti ẹyin mọ?
21/06/2026
Asiko islam titan nilẹ Yoruba, Afi ki wọn pada si Saudi nibiti oti wa, tori kosi aye fun Jagidi jagan mọ nilẹ wa, alafia lafẹ YES or NO?
Click here to claim your Sponsored Listing.
