Sheikh Qomordeen Ibrahim

Sheikh Qomordeen Ibrahim

Share

Adagba yowo kowo koni je tire ati emi,bi a bari eniti o sumo eni ti iru re nba sele si e pe number yii 0 :-08032093991

Photos from Sheikh Qomordeen Ibrahim's post 23/12/2022

AIDURO NI IJO,BI NKANKAN KO BA SE E,RI DAJU PE O NSE NKAN BI A KO SILO A KII DE,KI ALLAHU FUN WA NI ASEYORI,LORI GBOGBO ADAWOLE WA

01/11/2022
06/09/2022

Gbe ohunkohun toba ti ru e loju ju sile,se eyi to da e loju.

06/09/2022

Ilera loogun oro,toju ara a re.

23/08/2022

Alaafia Tayo
Moki gbogbo ile e ku asiko yii,ilera loogun oro eniti o lowo ti koni alaafia ogun ma nii,alaafia wa koni di fia - fia, Agbo yii wa fun gbogbo ailera tako tabo e wa baara meji e ge won keekeke sinu ike 5ltre e gun ewe asunhan oynbo pupa sususu,eko lee lori,oja ikooko bii meta e ko lee lori e tu oyin igan igo kan sii leyin ojo keta, gaasi kan ni a o maa mu.o dara fun onidaduro,ara riro,iha siso ati beebelo. Fun ibeere :- 08024434441 08154484459 .

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Ikeja?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Telephone

Website

Address

Number 14 Ago Sheikh Bolohunduro Alapata
Ikeja