Dr Adewale Ifayemi

Dr Adewale Ifayemi

Share

Igbinyanlo ju gbogbo inkan lo

12/06/2026

A Strong Crowd Puller for All Businesses

Items Needed:

1 ripe small pawpaw

9 round cowries

Cat's eye leaves

1 currency note from your country

3 bottles of Bintul El Sudan perfume

Preparation:

Make a small hole at the top of the ripe pawpaw. Place the cowries, cat's eye leaves, and the currency note inside the pawpaw.

Open the three bottles of Bintul El Sudan perfume and pour the contents into the pawpaw as well. After that, cover the opening with a piece of clean white cloth.

Keep the prepared pawpaw in your room overnight until the next day. On the following day, hold it in your hands and state your intentions clearly.

Finally, dig a hole anywhere within your home or business premises and bury the pawpaw there.

11/06/2026

AGBO EJE RIRU (HIGB BLOOD PRESSURE)
Eje Riru je Aisan ti o ma nseni niwon igbati Awon Isan ti o ngbe Awon Eje Losi Inu Opolopo, ti Awon Isan (vain) yi bati di, o sese ki Eje ki o Mari aye Lati koja lo si Inu Opolo, Ti Iru Ipenija bayi bati sele, o sese tlki Ifunpa Eni kino ma ga.

Ata Ile Pupa
Alubosa Elewe
Alubosa Ayu
Oyin
Omi Osan wewe

Ao fi obe la Awon Isan ti si Meji, ao wa se Gbogbo Awon Eronja yi papo ni Agbo, mimu ni Gass cup kan ni Emeji lojojumo owuro ati Ale.

Pelu ogo olohun oba, Gbogbo Ohun ti o nje Ipenija Ifunpa Giga (high blood pressure) yi o lo patapata ni.
Iwo na Bawa share re fun Anfani Awon Elomiran na!

Gbogbo wa konifi Aisan Logba

11/06/2026

Oshole okiki

Ori ologbo kan

Ewe sawerepepe

Eru Alamo

Ao gun gbogbo re papo mo ose ao ko ose ye sinu igba ao Fi eje akuko adie kan po ose ye papo ao Fi Ori akuko adie ye gun ose ye Lori leyin ojo keta wiwe lararo pelu adura

11/06/2026

LOOSING BONDAGE/BAD DREAM'S

Go and get white jetropha leaves that fell down( Erele lapalapa funfun) pick the one you see on the floor plenty and pound it with Anti witchcraft peel(Epo Obo in Yoruba) together with soap package the soap inside white plastic.
Use it to bath in the night before you sleep and also take palm oil to rub your body before bathing.

ATTENTION!
This also work for Bad dreams, eating , sleeping with man or woman in the dreams and loosing of Cobwebs also.

You can get all the Anti Witchcraft peel/ Epo Obo from people selling spiritual leaves or ask them they we direct you were to get that

Tested and Confirmed

Please Share to Assist

Prepared one is available

Call or WhatsApp
Dr Adewale Ifayemi
09056101690

05/06/2026

EYONU TOTUN SISE KI IKORIRA KURO LARA EYAN

Awon agbalagba ti wonda inkan ma ni gba igbinyanju dada ni won so wipe eyonu loba ogun..hun egbo beni abi beko? Mofi olohun oba toni emi mi bura losi asiri ti bafefi kale fun wa yi wipe atakere iyodun ni fun iwo ti olohun bani koba asiri yi pada dupe fun olohun kosi mafi oju di rara

Ti eyan base ise yi ti odetinlo ise yi gbogbo aiye ni yo ma yonu siyan ti eyan bani ikorira lara to balo ise yi gbogbo awon eyan lokunrin lo binrin omode agbalagba ni yomanife oluwa re...mioraye sodun pupo lori ise yi


Ao lowa ododo ewe misu ti awon eyan masi ododo ewe rerinkomi) ao lo kun na dada ao fi ori ko ao ko iseyi sinu ike olomori kan ao mafi ra idodo wa taba jadelo ati ale tabafesun...

05/06/2026

ASEJE ASINA TODAJU ๐Ÿ’ฏ
Opolopo lonsise sugbon ti koni Akojo Lori Ise na, bee, Opolopo ni ona dimo ti Atije Atimu wa nira fun, ti o ba gbiyanju ohun ti mofe salaye re yi, o damiloju wipe Ona masi fun o lase olohun oba.

Ponmo Ti I kako
Iru woro
Omundun Ewe Rere Oojo
Ata Josi Iyekiye
Iyere Iyekiye
Ewe Ola niwonba
#1000 New Note

Ao lo Gbogbo Awon Eronja yi papo, ao fise Aseje yi ni obe pelu Iyo.

Ti o ba jina, ao je ki o Tutu , ao wa so sori osuka, ao gbe #1,000 Tuntun (New Note) kale ao wa gbe Aseje yi lelori, ao Se Adura si bayi wipe:

Ewe Rere loni ki e ma fi Ire TEMI wami RI Lati Oni yi lo
Ewe ola loni ki Ona bere sini la fun mi Lati Oni lo
Aditu ni andi IRU, ti Omo Araye bara Iru loja, omo Araye a si tu Tiwon badele, ki Airije,Airimu, Airina, Airilo ki o kuro Ninu Aye Emi Lagbaja Omo Lagbaja Lati oniyilo ๐Ÿ™๐Ÿฟ

Pelu ogo olohun oba, ona masi, ona mala lase Eledumare ๐Ÿ™๐Ÿฟ

02/06/2026

EYONU IMULE TON MU OWO AWON AGBA KURO LARA
eree ikakue
epo-obo
oga gbigbe 6
eku asin 6
oka egoo kan
odd atare 6
ao jowon po ninu ape titun ao tun lo kuna lai kanle ao wa te ni odu 16 sugbon osa-meji ni yio gbeyin awon odu ye , ao wa ro itan re si nigba 16 tabi3 tabi ekan soso pere ao wa ro sinu ato kan tabi inu igo ff kan , ao wa ma fi se eyele dudu kookan je fun 16days lera lera , eyi ti a ba fe fi se obe na ao tun te ni awon odu 16 yen ao tun ro itan re si ao wa dasinu obe na , ao se lepo niyo pelu iyere ati omi , ti oba jina ao so kale laikan le aogbe pamo si aye owo , ao wa je ni idaji ojo keji lai ti fohun si enikeni,,

ITAN RE
iya tin fi idi soro loruko anpe eyin iya mi aje 3x
iya atobo soro loruko anpe eyin iya mi aje 3x
iya atobo jedo loruko anpe eyin iya mi aje 3x
won ni kie ma kala ejio 3x
won ni kie ma sodun ailoran3* eko e kala ejio, bee esi sodun ailoran, imule ba seji papo, won ba leyin lo sotu ife, lori igi iroko agun reke, igba ti e de ibe , ebi npayin, oungbe ngbe yin ,bee oju npon yin ,t**i gbogbo odu merindnlogun ba pejo, eni ki ejiogbe ojowo gbeyin de ode isalu aye,ejiogbe ni oun ko le gbeyin eni nitori kini ejiogbe ni ti oun ba gbe yin wa si isalu aye tan, isekise leo lo mase nisalu aye , e wa nbi ejiogbe lere wipe iru ise wo ni isekise ti awon fe lo mase lode aye , ejiogbe ndayin loun wipe nise ni eo lo ma pa awon omolomo je bi eran , ti eo si lo ma se awon ise buruku ni ejiogbe bafi ko lati gbeyin wa isalu aye, e tun pe oyeku meji oun na koyin , e pe iwori meji oun na koyin ,e pe odi meji ,oun na koyin t**i gboogbo odu merindinlogun fi koja ti won si ko lati gbe yin wa ode aye , ebi npayin oungbe ngbe yin bee oju npon yin, e wa bere si be osa meji t**i tie fi seleri fun wipe eo fun ni nkan imule yin, ni osameji wa bere lowoyin wipe kini awon nkan imule? ti eo fun oun atiwipe ise kini imule na yio ma se?, eni enikeni ti o bale je ninu ifa na, o ti di imule eyin aje niyen, eo si oju anu wo iru eni be ti eo si ni di lowo mo , eo si ma lana fun. osameji wan bi yin wipe kini nkan imule na? eni ki osameji o lo toju oga mefa, eku asin mefa,odd atare nla mefa, ko mu oka egoo kio jo po ki o ma fise eyele dudu kookon je fun ojo merindnlogun tabi igba merindinlogun, eni gbogbo eni to bale se bayi ti o si je be , eo ni fi enu aburu yin kan onitoun mo lai , eo si ma yonu si gbogbo nkan re,yio si ma yanju, ti gbogbo aye yio si mayonu si gbogbo oun to banse , eni toripe eyin kije oka egoo, enikan kisi fi eku asin bofa, beeni enikan ki fi oga bo orisa, eni gbogbo eni to ban bi abiku to ba je ninu obe na ko ni bi abiku mo, eni gbogbo eni ti ona badi mo ona yio si la fun, eni gbogbo eni to banse aisan ti ko san ,aisan na yio san yio si lo patapata, tabi eni to bandawo le nkan rere ti koyanju, tio ba je ninu obe na yio yanju,eo fi oju anu wo ,eo si mu owo aburu kuro lara eni na, eni toripe eyin aje ni
agbana, okuta,wahala, ejo, orogbese, ati orisiqisi adanwo. eni eyin ni e man ti okun bo eniyan lowo ,tofi jasi pe gbogbo ibi ti onitoun banlo nise len tele lo, ti eo si ba debe , ti eko fini je ko roju soju ara re ,ti koni raye saye ara re, e wa ni eni to ba ti wale je ninu obe ifa yi , onitoun yio bo ninu idamu yin, ti eo si mu owo aburu yin kuro lara re, ati ni ojo iwaju re, ni osameji bafi so fun yin wipe ki eje ki oun koko lo se obe yi fun awon omo oun, awon iyawo oun ati awon ololufe oun, ki oun to gbe yin wa sode aye , ni eyin aje ba palase pe kio se yio si maa je be, ni osameji na balo se, esi fi ase si. nitorina ki e je ki temi L omoL na o sise loni o, ni osameji ba pada wa gbe yin wa sode aye. nigbati e wa de ode aye tan gbogbo eni to je ninu obe ifa na wa bere sini re oun rere , oro won si dayo, won di eni ti en siju anu wo , ni omo araye ba nsanu won. ejika osi ni osameji fi gbeyin wa sode aye lojo na ,nkan imule ti e fi ba osameji mule ni ojo na ni emi L omo L na fi bayin mule loni o ki e siju anu
yin wo mi ji e yo oju buruku yin kuro lara mi......,,,,,.Adua.............
Rii daju wipe o dupe lori ifa yio
Yio bawa lara muo

31/05/2026

Now available in PDF
Call or WhatsApp
09056101690

25/05/2026

ASEJE OWO FUN ODUN TOBO WAYI

Momu aseje yi wafun eyin eyan mi ti e message mi lori what's app ati eyin tepemi wipe baba Adeshola ejo ari owo tafise odun ooo mani ki efi okan bale wipe tobadi oni Monday ti odun baku jometa ni mofun yin asiri aseje kan tomomu owo gidi wa tobere lati 50k losoke...wallah mofi olohun oba toni emi mi bura lori aseje yi wipe gbogbo iwo ti oba we orisiri tude bi meji si meta kowaje aseje yi ahhh wagba owo re kiakia eyan onije aseje yi komagba owo...wallah aseje todaju tomu owo wani sungbon olohun obami daju julo...pelu ogo olohun ao ba anu olohun pade lara ise amin ๐Ÿ™

ASENA RE
Ao lowa ewe rere ako ati ebo ojo atojosin 16 ewe ola die ao lo papo ao lora eja aro totobi dada kan ao ge eja na si ona meta ti kogbodo geja ao fi awon eroja taloyi se ejayi lepo ni yo koko tuntun nla kan lalo oo ao so aseje yi sori osuka kan ao lowe ose atude kan tabani nile kan ao wase adura si dada ao ko aseje na se leyin na ao mu omi aiye kan lelori...humm ejeki amareti owo loku baye

Ejekifun wa ni ose atude kan..kalowe katoje asejeyi

Ao lowa ayan inu salaga ati ayan towa ninu baluwe wa ao lo pelu รจpo obo die ao koni ose iwe kan ao lowe tabawe de ao loje aseje ye bayen

24/05/2026

AGBO LOW S***M COUNT
Opolopo Loti ndamu Lori Aisan yi, bee, Oniruru nkan ni o ma nfa Ipenija Aisan yi, Opolopo tise Oniruru Ayewo (Medical test) sugbon Tiwon so fun wipe Ato (S***m) re kole di Omo Rara, ti Eyi si fa ibanuje fun Opolopo.

Mofi nda e loju wipe ti o ba gbiyanju ohun ti mofe ko o yi, mofi oba Ti o da Ewe Ati Egbo se eri, Ato (s***m) na yi o di Omo.

OHUN TI AOWA
Ewe Abo Tutu
Isu Aidan
Omi Osan wewe
Omi

Ao fi Awon Eronja yi nu ki o mo dada, ao wa ge Isu Merin ti o Wa Lara Aidan yi, ao gun dada, ao wa gun papo mo Ewe Abo Oojo yi, so re (soak) sinu Omi fun bi Ogun iseju, ao Se (filter).

Mimu ni short cup kan, ao ma bu Omi Osan wewe Sibi meta si ao ro papo, Lesekese ni Agbo yi yi o yirapada ti yi o dabi Ato (s***m).

Ki a ma mu ni owuro ati Ale.

Pelu ogo olohun oba, ti Eniyan bamu Agbo yi fun Ose Merin lera lera, ki o pada lose Ayewo Nile iwosan, Ato (s***m) na yi o ti ni Eyin Ninu ti o le di Omo.

Iwo na Bawa share re, ti o ba ri Anfani kan Ninu Ohun ti mo nko e yi.

Gbogbo wa konifi Aisan Logba oo ๐Ÿ™๐Ÿฟ

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Osogbo?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Address

Osogbo