Yah Ghaffar herlb
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Yah Ghaffar herlb, Health/Beauty, At shapon area ago oko, Abeokuta.
28/10/2020
ASEJE BIBO ASIRI TO WA PA
Ewe ela, ewe sawerepepe, ewe tonnapowo, ao lo ti yio kuna dada pelu iyere, ao fi se Igbin nla agbonu kan ni aseje lepo niyo.. Ao je laro kutu hai pelu adura
Ajegun re sope asiri mi onitu lailai
Ogun atude to yara lati tu gbogbo ide..
Ao han ayayi وإذيمكربك الذين كفروا ليثبتوك أو يقتلوك أو يخرجوك ويمكرون ويمكرالله والله خير الماكرين ١١١....
Ao tun han ما جئتم به سحر ان لله سيبطله إن الله لا يصلح عمل المفسدين ١١١ ao wa Egbo tude ewe tude,egbo ajeobale ati ewe re,ewe Akoko ati egbo re ati epo re pelu ata ijosi pupo ao gun kuna ao po lose pelu omi hantu yen ati lofinda bintu sudan original meji ao maa fi we
Comment koba leje fune Bawo lase mawe labe comment
Ise iferan todaju
Ise yi wulo fun gbogbo eniyan yala oga si omo ise abi omo ise si oga re, oko si Iyawo abi Iyawo si oko re papa julo fun awa onise owo ati Kata kara
Ise na lo bayi :ao ra agbon ao jo omi re sinu abo kan ao fi omi agbon yen gbo ewe imiesu ati ewe owu ekese oojo, ao se idoti re, step 1,niyen o, ao wa han oruko olohun yi :WA'ALIKEITU ALEIKA MUABATA MINI 111, YAH WADUD 111, YAH BADUHU 111, YAH HADI 111
والقيت عليك محبة مني ١١١
يا ودود ١١١
يابدوح ١١١
ياهادي١١١
Ao fi omi agbon yen ti ati fi gbo awon ewe yen fo ao wa da perfume orisi meje si ao maa fi pa Owo ati oju wa. Koda ti eni ti oni ikorira lara balo olohun yio da a*o ife bo iru enibe ti yio si di eni ti gbogbo aiye yio maa feran. fun ose tabi ipara re 08089880824.or comment labe re🙍🙍🙍🙍
Isora nitori awon Ole
Opolo oye nla kan ao ko oruka si lenu, ao ko ayare soke ao wa fi atare kan si laya ao gbe okuta le, ao jo, ao ma fi oruka na ko enu ona
24/04/2020
Eyonu gidi todaju
Opolo ijokun kan, ewe ewuro oojo, atare kan ao jo papo ao maa fi fo eko tutu mu ni ale kato sun
17/02/2020
ise yi dara gidi gan fun itaja
Ewe ola pupo, ewe rere ako ati abo, ao ti yio kuna dada, ao fi omi agbon po lose ao ko ose na sinu atupa amo, ao fi abela pupa kan gun lori ao ma we ose na fun ibeere lori ose na 07066460285 ti eba fe ka Se funyin #5000 pere ni Wibe jebe ti Oluwa ni
10/02/2020
Agbo atosi ati inurunrun
Osan were to gbe ati enu opire ako Kahun ao jo papo ao maa fi foko tutu mu fun alaye lekunrere dm me
04/02/2020
Ogun ifo /ela
Ao mu ose dudu ibile, kohun ti anje, omi osan were, epo gbogbo re papo kie maa fi paa.... Wibe jebe ti Oluwa ni. Eo yin oluwa logo
Awure oshole todaju :-
Ori oka kan tope, ori olufa kan tope, ewe aje, ewe etiponla, ewe etiponla abifa gburu, ewe ito, eha okuku ala*o, ao gun gbogbo re papo, ao po lose ao ko ose na sinu awo funfun, ao fi ikode kan, iye agbe, iye aluko gun ose na lori (otan). Ohun re :-
Ile loka joko ti onje re nba, ile lere njoko ti onje re to, ile lala*o joko ti okuku nwo to, gbogbo ara ni sefunsefun fin sowo tie, etiponla abifa gburu, ito loni kin to ara iwaju, igbongbon loni kinju ero eyin seyin, loni kinju ero eyin lo, kojo loni ntojo, enia mimo awon oyinbo ki wan ma wa fun mi lowo, ao se Adura si dadaa ao ma we........ Wibe jebe ti Oluwa ni لا حول ولا قوة إلا بالله العلي العظيم
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Telephone
Website
Address
At Shapon Area Ago Oko
Abeokuta
