Wamiq Prophetic medicine
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Wamiq Prophetic medicine, Health/Beauty, Wasinm Araromi Close isabo, Abeokuta.
23/08/2024
ASIWAJU TONSE NKAN OSU (
MENSTRUATION)
Gbogbo wa lamo wipe nkan osu obinrin ni anpe ni menstruation, tosi je nkan egbin buruku tonjade lati ara obinrin ni ososu gegebi adamo won lati odo olohun oba swa pelu idi kan tofa sababi e.
Sugbon nkan mewa eyiti alefi se apejuwe gegebi nkan egbin lara eniti obaje asiwaju eyiti oni awon IWA wonyi lowo, iru asiwaju bee onse nkan osu nii.
1) Asiwaju tikii ni amojukuro nibi awon yodoyodo aye.
2)Asiwaju tikii ni suuru fun awon omolehin.
3) Asiwaju ti obani oju kokoro owo tabi ojukokoro obinrin .
4) Asiwaju tikii baa ni aanu awon Omo lehin re.
5) Asiwaju ti iro (lier) bati Jamba re.
Asiwaju tikii baa so ododo tabi se ododo laarin awon omolehin re.
6) Asiwaju toba ya ahun (stinging).
7).Asiwaju toba ya alabosi tabi munofiki.
8) Asiwaju tiko bani Itiju
9) Asiwaju ti kii ba nmu Adehun se.
10) Asiwaju tiko bani Agba pamo, Amaana (Trust) Abbl.
Awon wo gan ni anpe ni asiwaju gannnn.
1) Imaam tabi Amir, tondari Wa ninu ijosin ni mosalasi (mosque)
tabi ninu ijo (society or organization)
2) Pastor tabi Alagba ninu Ile ijosin (church)
3) Adari ilu, bii president, Governors, Chairman local government, C D A chairman, Olori ebi (head of family) Oga Ile ise tabi oga Ile eko eyikeyi, ati gbogbo ona eyikeyi tio bangba lati maa je asiwaju lawujo
Gbogbo enikeni toba tin hu iru awon IWA timoka sile yi, iru eni bee ELEGBIN ni lodo awon Omo eda enia ati ni odo olohun oba.
Ejeki ayago fun awon IWA wonyi, ki aleje enia pataki ati eni aponle lodo olohun oba swa.
Lati Ori tabili Ile eko AMQITC
06/08/2024
03/08/2024
03/08/2024
03/08/2024
03/08/2024
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Wasinm Araromi Close Isabo
Abeokuta
