ONA Aseyori EDA
Aseyori ni tiwa
ako alangba aye 9
Abo alangba aye 9
Eyin ibile tomo dada 9
Ogede omini topan 9
Odindi Atare 9
Kerewu topo
Eru Alamo agolo meta
Epo Obo niwanba
Aojo gbogbore papo, aomafi mu Eko yangan (ogi Agbado funfun) pelu ori abi milk abi Oyin, eyikeyi tobawuwa ninu awan nkan meteta yi ni aodasi inu ogun Yi pelu ogun ti abati, aomamu ni aaro.
Odaju, aonifejeki ogun Yi tan MA ninu ile wa.
Awure Owo Olosekan
Ao wa oga gbigbe ti irure ka dada
ao ra isasun tuntun olomori
kekere odidi atare kan ao fi atare
kan si legbe ao jo ao lo ra a*o
funfun opa kan kio te sile ki owa fi
miliki olope kan lo lori a*o funfun
ati koko ati a*o yi loju si ori atan.
Ona owo yio si fun o kosi aburu
kan kan lori iseyi
NB: ti yio ba je funo isere koju
osekan lo, Ale se ise yi lojo lasan
sugbon ojo sunday lodaraju ijo
tabajo lagbodo lo. %%%%%%%
Lati owo Emi Omo yin nani Dr . IFADIPE IFAMUYIWA AYOOLA OMO AJE NATIONAL SECRETARY OTITO LOGUN PRESIDENT ONA ASEYORI ONA Aseyori EDA
OSOLE TUTU TI O DAJU JOWO DANWO KI O FUN ILE LABO RE
Eye igun tutu kan Ao la ayare Ao ki OGA kan bo ni okan aya re pelu oromo diye kan pelu alangba
adaripo kan ati alayunbere kan pelu omole kan ati odidi atare kan awe omisimisi pelebe pelu
gogoro ewe aje ewe ajeobale pelu abamoda ewe sawerepepe ati ewuro ojoo ao koko ki awon
abemiyi sinu igun yen pelu iwoba ewe tio bale wo inure Ao wa ko ewe tioku yele lori Ao wo Jopo
Ata ijosi ni ao mafi ko inare ti abajo tan Aolo Aoma Mu edun ara Ojuda aola si meji Ao lo idaji kun
na Dada ao dapo mo ebu Ogun yi aosipo ebu yi mo ose dd tan patapata ao ko oose yisinu igba
olomori NLA kan ao wa fi edun ara abo yen gun ori ose yen pelu edan Ako pelu obo si NI egbe
mejeji Ao wapa pepeye ako ati ao to aoro ejewon so ori ose yen aode fun ojo meta Ao maweni
Dede agokan oruuu.
114 IMULE AWON AGBALAGBA
aowa eye olofere eyonkan,aoweni owu dudu tioni han sitamon ao gbe sinu ape aofi atare kan
silegbe aowako igbe adie lelori tiyiopo die aojopo aomafi ogere epo pupa lani ago kan oru
(ikilo)obinrin ko
gbolo ninu ise yi oo
RI Daju wipe o se IMULE ise yi ki o to lo ise yi o ti ma lo IMULE yi ni ojo meta tele rawon ki o to lo ise yi
*TI ISE KOBA LODEDE*
*AGBON NLA MEJI,EPO OBO, ISASUN OLOMORI TUNTUN....AO GUN EPO OBO KUNA DAADA AO DA SINU ISASUN YI AO DA OMI AGBON MEJEJI SI AO RO PAPO DAADA,AO GBE KANA KO HOO DAADA AO WA SOKALE AO DA OSE DUDU SINU RE AO FI SIBI RO OSE YI NINU ISASUN YI DAADA,AO GBE SI IGUN ILE AO MAFI SIBI YI BU WE NI OJO WEDNESDAY ATI SATURDAY NIKAN*
*AWERO ITAJA*
*PONRI KAN,EWE GBEGBE OOJO, ODIDI ATARE KAN AO JO PAPO AO LO TIO KUNA DAADA AO RO SINU IKE OMI KAN AO MAFI WON OFFICE ABI SHOP WA*
*EYONU AWON AGBA ATI APAMO OWO*
*IKODE META,ALANBERE META, ODIDI ATARE META ODI JIJO AO FI SIN GBERE YIKA ORUN OWO WA MEJEJI ,AO PO EYI TOKU MO OAE DUDU AO MAFI WE LARARO*
*LATI OWO EMI OMO YIN IFADIPE MUYIWA AYOOLA OMO AJE*
OSOLE TUTU TI O DAJU JOWO DANWO KI O FUN ILE LABO RE
Eye igun tutu kan Ao la ayare Ao ki OGA kan bo ni okan aya re pelu oromo diye kan pelu alangba
adaripo kan ati alayunbere kan pelu omole kan ati odidi atare kan awe omisimisi pelebe pelu
gogoro ewe aje ewe ajeobale pelu abamoda ewe sawerepepe ati ewuro ojoo ao koko ki awon
abemiyi sinu igun yen pelu iwoba ewe tio bale wo inure Ao wa ko ewe tioku yele lori Ao wo Jopo
Ata ijosi ni ao mafi ko inare ti abajo tan Aolo Aoma Mu edun ara Ojuda aola si meji Ao lo idaji kun
na Dada ao dapo mo ebu Ogun yi aosipo ebu yi mo ose dd tan patapata ao ko oose yisinu igba
olomori NLA kan ao wa fi edun ara abo yen gun ori ose yen pelu edan Ako pelu obo si NI egbe
mejeji Ao wapa pepeye ako ati ao to aoro ejewon so ori ose yen aode fun ojo meta Ao maweni
Dede agokan oruuu.
114 IMULE AWON AGBALAGBA
aowa eye olofere eyonkan,aoweni owu dudu tioni han sitamon ao gbe sinu ape aofi atare kan
silegbe aowako igbe adie lelori tiyiopo die aojopo aomafi ogere epo pupa lani ago kan oru
(ikilo)obinrin ko
gbolo ninu ise yi oo
RI Daju wipe o se IMULE ise yi ki o to lo ise yi o ti ma lo IMULE yi ni ojo meta tele rawon ki o to lo ise yi
Lati OWO EMI omo yin na ni DR Ifadipe Muyiwa Ayoola omo Aje nani ooo Moseba Agba kin le to Agba oooo
OSE OSHOLE TINGBE ALANU PADE.
👆👆👆👆👆👆👆👆
Ori oka to ni ase lenj kan.
Ori ere to ni ase lenu kan.
Ori agilinti kan.
Ori akuko adie to gbo daada kan.....opolopo ewe anu..tutu tabi gbigbe
Ori obo to kpe daada kan.
Apoti ti afi igi iroko kan.
A*o funfun ilaji opa.
Otin schinap kan...ose, ao gun awon eronja yi papo(ori oka, ere, agilinti, ori akuko adie, ewe anu) ao gun awon eronja wonyen papo mose, ao fi oti po gbogbo papo morawon daada, ao wa ko ose na le obo ( tabi ki afi ose na bo gbogbo ori obo na patapata).
Ao fi a*o funfun die bo ose na tio wa lori obo yen, ao the a*o funfun die sinu apoti iroko yen, ao wa gbe ose na le ori a*o funfun ti a te sinu apoti na, ao de apoti na pa fun ojo meje.
Lilore:- ao koko fi otin die pa gbogbo ara wa, ao wa lo fi ose na wa ni baluwe pelu adura anu ore owo nla fun wa.
Akiyesi:- kainkain ibile tuntun kan pere ni ao ma fi we ose na, ao si ma fi kainkain ibile na le ori apoti yen ti aba ti we tan...ako gbodo wo bata ninu baluwe ti a ban we ose na lowo. Ako gbodo ni ibalopo kankan rara ni ojo ti aba ti we ose yi.
Emi Omo yin nani Dr. Ifadipe muyiwa AYOOLA Omo Aje
OGUN FUN ENITI WON JEKI OGUN JE FUN MO
Igbin kan,ao bu iyo sile ti o ba ti yori ti o fi enu kan iyo yan to bati ku,ao wa yo kuro ninu ikalahun re,ao wa gun igbin yan po pelu epo obo,ati erupe orita meta,ao wa gun mo ose,inu odo la o ti gun o,ao ma we ose na,won a yoda wa kia,Ogun asibere si sise Lara eni,won ni ba ise tabase je mo,odara gan ni o
*IMULE OSO OWO TI A NFIN JA SI AWUJO AWON AJE*
👇👇👇
E o wa ori aja tonirun kan , ori owawa tonirun kan , egbo iyeye , werenjeje agolo kan , ori oka kan, odindi atare kan, isu gbegbe, egbo botuje funfun ati eka ewe re die , ape ijoogun tuntun kan, sere kan to tinrin ti ko tobi pupo , awo ekun die , awo ijimere die
*SISE RE:* E o ko gbogbo awon eroja yi sinu ape yato si awo ekun, awo ijimere ati sere yi, ao jo, ti o ba ti jo tan , ao lo papo kuna daada lori olo ti ko kanle Eo wa ro sinu sere yi , ao fi awo ekun di lenu Eo tun daa idi sere yi luu ni isale , ao fi awo ijimere naa di Eo gbe pamo si aaye owo ti ko gbudo kanle mo lailai....LILO RE ...ti a ba daa ebu yi lati enu seere yi tina fi awo ekun di , ao ma ri owo gidi. Ti a ba loo oogun yi lati idi ti a fi awo ijimere di , yio ma sise imule Eo ma lo lati idi ni ale patapata pelu epo pupa , ao si ma loo laaro lati enu pelu hot to lagbara Eo ma ri owo , yio tun ma sise imule lara wa Eyin eniyan mi , ti e ba loo oogun yi fun ojo meje , dandan ni ki e ba arayin laarin awon agba ti won ti nse ipade oo. Eo dijo maa je , eo si dijo maa mu ninu imule kanna , won ko si ni da eniyan laamu mo ninu aye mo fe ki e roo daada ki e to se oogun yi o. Nitori eniyan ki ko sinu omi , ki o tun ma kigbe otutu o ti o ba ti loo oogun yi , iwona ti di ara won niyen o ...!
A ku ojo meta ooo owo omo yin lodi oooo sugbon e Jeki a fi Eleyi sere Lara awon tested confirmed ti mo ti danwo dada ni
APE OBINRIN
ao wa oju oro pelu osibata pelu afomo igi ti abari ao lo papo mo iyere ao fise igbin odidi kan je
lepo ni yo ao wamu iyere osun ao fi te ifa ejiogbe ao mawa pe ohun _oju oro kiya omi_osibata
kisileyin odo oju mi to lomu afomo ranmo igi koleja ki l omo l omaja leyin emi l omo l ejiogbe
walogbe ife emi l omo l si okan l omo l ti kobarimi komale sun komale wo obe ti emi l omo l oje yin
inu l omo l ni kolosolesi toba denu re koma ni ife mi ao wa da iyare osun yen si nu obe yen ao
wa koje p**e gbogbo omi obe re
62 ASEJE EBE AWON AGBA
Ewe ewuro ewe oriji ewe ajeobale igbin NLA kan ewe tanaposo ao lo ao fi se igbin ye je ao fi iyere
osun Te IFA osa meji
04re::,akeshasha akeshasha orabaju baju ka ilu akeshasha ora bajubaju ka ilu abi lobo ati obo se
oro ati obo ja ati obo mu eje obo lobi yin lomo obo lobi Emi na lomo omo obo kin ja omo obo loro
EMA dimi lowo EMA dimi lese e ma di ona ririse mo Mi mo ode nikie fimi si Agba ni kie fimi se igi
po Ninu Igbo ki orisa tofi ewuro se Agba igi ewe oriji loni kie fi ohun gbogbo jimi tanapowo loni ki e
je kin ma ri towo se ile aye Mi aje kan kin bale ewe ajeobale ki aje male bale Mi kiwon ma le bami
ja ire ni kie ma se fumi nitori odidi odidi LA hee igbin Ninu Igbo osa meji o3* wa ma sa nkan
buburu kuro Lara mi osa meji ire tinbe Lara Mi wa lo ma sha fumi ao da si ao je
Lati owo emi omo yin na ni President ONA Aseyori EDA DR Ifadipe Muyiwa Ayoola omo Aje nani ooo Moseba Agba kin le to Agba oooo
Elo get odd ere1 ti o pe dada.ologini dudu1.ina ori yunyun pupo.eku afe1,iye agbe3,iye aluko3,ikode3,oga gbigbe3.e get tuntun ewe ti a lu ti o parada201.ewe sefunsefun201 pelu odd otaraba eyikeyi ao jopo ni dede ago1 oru ao fi adin eyan yika aro.sugbon ao gbudo si tabi ro ti yio fi jotan o ti o bati jotan ao pa adie funfun1 sile ao wa so iseyi sori eje adie yi t**i yio fi tutu ao ro sinu sere nla 1 ti a ti fi a*o waji pawo re da ao wa ran asunwon a*o funfun ao gbe sinu re ao fi 1000 sibe leyin ojo meta ao lo sibe ao ma ko 100,000 nidi re lojo metameta
ofore pelu etutu re ti o ba da ara re loju awon ti whatsapp ti mo bi iseyi seni agbara to all tested
ASEYORI NI TEMI
EMI NANI PRESIDENT ONA ASEYORI EDA NI OOO
Ao lowa ori aguntan tutu ao wa ko gbogbo owo ti a na ni orile ede ti kowa wa bawa si lenu pelu odd atare1 ao gbe sinu ape tuntun ao so detu aolo ki o kuna dada ao wa ma fi oti sinapu lo lararo pelu gbolohun re bayi wipe
o4ore: owo a bo laguntan nke3*
e mowo temiwa funmi loni ojo ti a ba muti ni oti pani,ki eniti mo mo ati eniti mio mo bere sini ko owo temi wa funmi loni3*
ODAJU PUPO
:AO MA MU OTI NA TI YIO PAWA O
LATI OWO EMI OMO YIN NANI PRESIDENT ONA ASEYORI EDA NANA
AKU EWU ODU TUNTUN OOOO GBOGBO ILE SE EO BINU WIPE AO FI NKAN RANSE MO SINU IYARA YI TORI AWON COPY&PASTE NI O ATI WIPE OWO DI NI O
OHUN TIMO TUN RI NINU ILE YI NI WIPE AO KI N DAN ISE WO MO SI FE KI ORUKO EGBE YI ROWA ( )
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Telephone
Website
Address
Abeokuta
