Irawo ati aboyo ninu ishoro
This group is created for enlightenment of humans base on the secret about stars(Irawo) we use in life and steps to take to be successful in life
ASIRI BIBO TIPATIPA TI AFI RI OWO GBA LỌWỌ CLIENTS WA..
ẸYỌNU A
TUDE
ASINA
.......
Epo obo die
Ewe ewuro 16
Ike funfun olomori
Oyin gidi
Ose dudu tabi eyikeyi ose ti o ba wunwa
Aogun epo obo yii,aowa dapapo pelu ewe ewuro 16,ao wa gun mejeji papo tio kunna,aowa po papo pelu eyikeyi ose daada,
ao wa sẹsẹ daa oyin sibi 3 lati po ose yii papo,
aowa ko sinu ike funfun olomori ao de pa Di ojo keji
Odi wiwẹ
IKILO PATAKI:
Alale nikan ni a le we ose yii.
Ao gbọdọ we ose yii ni awon ojo meji yii,
Ale
Wednesday and Saturday
Salam aleikum
Is been long
What can we talk about
Is December period
Let's watch out
*let's use this a long time greetings BTN ourselves
ASEJE ASINA*
Ewe orijin ao lo po mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se igbin je ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Ewe gure ewe onitikuti ewe sawerepepe ewe Igbo ao lo po mọn ata ìjọsìn mesèn ao fi se eyin adire agiriki merin je ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Ewé àjé ewe sawerepepe ewe Igbo ao lopo mọn ata ìjọsìn mesèn ao fi se akuko adire kan je ao ge sí 16 ao sè ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Ẹjẹ arọ kan ao gesi meta ao ni geja o ao wa lo ra ẹyẹ onbe mẹta ao lo po mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se ẹjẹ arọ na je ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Omudun ewe ipin mẹsan omudun ewe lapa funfun mesan ao lopo mọn iyere mesan ao fi po eyin agiriki meta ao ro sí inú ọra kan sọ se ti oba jina ao fi ipepe ge eyin yẹn sí mẹta ao se adura sí ao je
*ASEJE OWO*
Eyin pẹpeye meta ao kò sí inú isasun ao dà omi agbani sí ao fi se jena ao jeki omi yẹn gbe mọn lara ao se adura sí ao je
*ASEJE OWO*
Igbin eyo kan ao ge sí 80 itana sawerepepe 80 itana tanapowo 80 ao lo po mọn ata ìjọsìn ao fi se igbin yen je ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Iṣu idi tanapowo ao lo pomon iyere mesan ao fi se adire akuko kan je ao ge sí 16 ao fi iru sí
*ASEJE OWO*
Ewe bomubomu 16 ao ko meje tele inu isasun ao ko eyin agiriki merin le ni ori ao ko ewe yẹn mesan le ni ori ao gbé ka iná ao ni bù omi sí óò yíò jina fún rare ti oba jina ao ko ewe yẹn kuro ao je eyin yé ao wa gun epo eyin yẹn mọn ọsẹ ati ewe yẹn ao mọn fi wẹ
*ASEJE OWO*
Egbo iyipo ola ao lopo mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se eren ewùrà ekiri mesan je pelu ata ìjọsìn mesan ao se ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Ekiri ẹran malu mesan ewe sawerepepe ewe aje ao lopo mọn iyere mesan ao se ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Onbe mẹta ao lopo mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se abo adira dudu je ao ge sí 16 ti obe na bajina ao gbé sí orí ibi to ba gan ao jo kò ni ori apoti ao gbé esane wa me ibikan to ri ese wa ko gbodo kan ile ti u be aba je obe yi lowo ao se adura sí dada ao je ale ni ao je obe yi ooo..
Is been long lovers
What can we post
ASIRI YASIN TODAJU...
Adua yii dami loju paa o si wa ninu ohun ti mo ma sa daada fun ara mi ati customers fun ohun kohun taba fe,eyin agbalagba npe ni "يس قهقهري" won Atun ma pe ni "سبعة الؤضوء" Aluwala meje lama fin sa.
Ao koko se mu kodimo bayi leyin aluwala wa.
استغفر الله ٧٠ الصلاة ١٣٠ الآية الكرسى ١١ سبحان الله والحمد لله ولا الله الله أكبر ٧. ولاحول ولا قوة الا بالله العلي العظعيم.
Ao wa daniyan
(1)Ao bere yasin taba de ibi mubinu ao duro se adua yii
الحمد لله رب العالمين ١٠٠٠. للطهطيل ١١١(Lali-Toha-Tihilu). صلاة تنجينا ١٠ .
Ao lo tun aluwala se.
(2)ao tun yasin bere lati ibere de mubinu elekeji ao tun duro se adua yii.
الحمان الرحيم ١٠٠٠. مهطهطيل ١١١(Moha-Toha-Tihilu). صلاة تنجينا ٢٠
Ao lo tun aluwala se (3)ao tun yasin bere lati oke de mubinu keta ao tun duro fun adua ibe.
ملك يوم الدين ١٠٠٠. قهطهطيل ١١١(Qoha-Toha-Tihilu). صلاة تنجينا ٣٠.
Ao lo tun aluwala se lekerin
(4)ao tun yasin bere taba de mubinu elekerin ao se adua re
إياك نعبد وإياك نستعين ١٠٠٠. فهطهطيل١١١(Fah-Toha-Tihilu) صلاة تنجينا ٤٠.
Ao lo se aluwala karun
(5)ao bere yasin lati ibere de mubinu karun awa se adua re
إهدنا الصراط المستقيم ١٠٠٠. نهطهطيل ١١١(Nah-Toha-Tihilu). صلاة تنجينا ٥٠.
Ao lo se aluwala kefa
(6)a bere yasin lati ibere de mubinu kefa ama se adua re
صراط الذين أنعمت عليهم ١٠٠٠ جهطهطيل ١١١(Jah-Toha-Tihilu). صلاة تنجينا ٦٠.
Ao lose aluwala ipari
(7)ao tun se yasin lati ibere de mubinu keje ao se adua re
غير المغضوب عليهم ولا الضآلين ١٠٠٠ .لهطهطيل ١١١(Lah-Toha-Tihilu) صلاة تنجينا ٧٠.
Ao wa sese tun yasin bere lati oke ao ka pari o tan Kosi nkan tasa le lori ti ao ni rii yala lori owo ni,oore kan ni,alare ni,iyawo fife ni,isora ni,isegun ni tabi nkan Miran .
Longest days my beloved family
Thinking of what to post
Pls make a suggestion
BEEN THE FISRT DAY OF ISLAMIC CALENDAR
MUHARRAM FIRST
LETS TRY THIS
EYONU ASINA ATI AWORO ITAJA TODAJU.
1
Ao gun ewe ewuro oojo nikan ninu odo, tiyio Kuna daaada, ao wa gun mo ose dudu, ao wa fi lofinda bintu po papo daaada, ao gbe pamo fun be 3 days leyin 3 days odi wiwe laro laro
2
Aogun ewe ewuro lodo dada tio kunna ao po moshe dudu
Ao gbe ori (share butter)sinu orun tio yoro daada ao wa fi owo wa po mosheyi ninu ike or
Kagbe Ori yi sori oshe tatigun pelu ewuro
Kawa gbe si orun
Tabati poopo tan ao mofiwe laro laro
OLOHUN BAMI FI ALBARIKA SI BIJAHI MUHAMMAD ROSULLULLAH ...
If u need something like this why not join this page
And let's make life easy for ourselves
What if we make things easier
Let's join hand together and try maybe
Group prayer
Oshole,
Imule eyonu nla
Isori apota
But with one condition
We all need trust among ourself
Location is very important
As per d supply
If u agree
Let's vote and bring our suggestions
14/07/2023
Is Friday
Pray all the best with success
Aseje bashiri to daju
Ewe kakasenla aolo pelu ata ijosi 16
Ponmo aoge si meta
Ogede agbagba/dodo eyokan aoge si meta
Eja shawa aoge si meta
Ao se laseje pelu epo ati iyo
Odi jije
Iyanu olohun mashele funwa Insha Allah
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Ita Elepa Agaka Ilorin
Ilorin
