Tito TV
TÍTÓBI NI OLUWA OLORUN KOSEUNTI
22/07/2026
Ogun a fí àkókò ẹni ṣòfò nínú ayé gbogbo ìwọ to rí Amin se ní Àsẹ Olódùmarè ina olorun le jáde Àmín
22/07/2026
Gbogbo ìwọ to rí àwòrán yí to sì rí Amin se Àánú kò ní ṣe tí ẹ tí láṣẹ Èdùmàrè Àmín loruko Jesu Kristi
22/07/2026
Ki oṣù yí tó parí èmi àti ìwọ má gba ÀLEJÒ ayò Amin loruko Jesu Kristi 🙏🏻
Ojú Ayọ tú tí mọ loni o bí O tiún jáde lọ kongẹ ibí ko ni jẹ ìpín gbogbo wá láṣẹ Èdùmàrè Amin
Gbogbo iserere tí Ayé tí fi ọganjọ òru gbà lọwọ èmi àti ìwọ ní Àsẹ Olódùmarè ina Olorun gbà padà fún gbogbo wá Àmín 🙏🏻
22/07/2026
Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard!Thank you so much God bless you all Amen Serah Omotayo, Francis Olusegun Falade, Subomi Ajoke, Michael Abiola Yak, Carla Cucul, Oyejoke Atiba, Adesanya Joshua Adeleye, Pst Sherif O. Akinyoola
Orun ayò là má su ọfà àwọn ẹni ibí kò ní bá èmi àti ìwọ tomotomo tebi tara wa loju orun láṣẹ Èdùmàrè Amin
21/07/2026
21/07/2026
Ìmò ọtá di òfo lórí rẹ tomotomo láṣẹ Èdùmàrè Amin
21/07/2026
Olódùmarè rántí mí sí RÉRÉ àti gbogbo ẹni tí rí àwòrán yí Amin 🙏🏻
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Address
Lagos Harbour
11011
