Iwosan ibile
for spiritual healing
06/05/2025
WHATSAPP NO..+2349152323888.
Eku ojometa gbogbo eyin ololufe iwosan ibile,
Atunti mu ise aiperi ti ojewipe ti enikeni ba peri iwo ti oba ni iseyi lara yo fi emi arare dii ni.
ISE NAA RE.....
Ao ra eyele dudu kan, eepo obo ti ofe to atelewo, obi iwarefa kan.
Sise re.... A o ko gbogbo re odi inu igbo, Ao gbele aofi eepo obo yen tele, Ao du eyele naa ni orun Ao gba eje re si ori obi iwarefa ti ati fi sinu ike kan, ao ju oku eyele naa si inu koto ti ati fi eepo obo tele re, Ao yagbe lee lori, aofi ese osi ro yepe boo, aofi ese osi kii mole daada, Aogbe obi yen si inu ile fun ojo meta,ao gun obi yen lodo aopo mo ose dudu ti alefiwe fun ojomeje, aora kainkain ibile meje, ao fiwe fun ojo mefa kainkain kan ojokan, ti oba di ijokeje ose toku pelu kainkain eyokan toku, aolo rimole ni ojuona ti awon eniyan nrin, opari.. mase enikeni nika, ti enikeni ba peri re yori eyele dudu ti oba ti rii, gbogbo asasi ati eedi tobaran siwa yo pada si ori re tabi ori omo re, ti koba jawo toba tun nperi wa di eemeta eje re yogbe lojiji yosi rare ku. ODAJU...
12/03/2024
Whatsapp no 09152323888.
12/03/2024
Iwa loba awure toju iwa re
12/03/2024
Aku ojometa gbogbo eyin ololufe iwosan ibile
E oni tenu gbo bi
06/07/2022
Aporo ofa ajebiidan
Fun ofa eyikeyi, WhatsApp number 09152323888
Aporo ofa eyikeyi. Owanle fun tita
01/07/2022
Aporo ofa eyikeyi. Owanle fun tita
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
No5 Bradford Lane Off Ibijoke Street Oregun Ikeja Lagos
Lagos
100001

12/03/2024