Emiola spiritual clinic
FUN IWOSAN GBOGBO AISAN ATI ISORO
Aseje ebe awon agba
Ewe ati egbo AJEOBALE,,ati ewe ati egbo ORIJIN ,, ataijosi die aolo papo aofise eyele funfun kan ti agesi 16, lepo niyo aoje pelu adura
Aseje asina
Awo EKUN die ,,obe kan ,,oga gbigbe ibile kan ,,1000 new note,,ataijosi ______ aolopo aofise Ori ogunfe kan aogesi 9 or 7 aose lepo niyo aokoje a*o tobadara ni aowo je
Ose eyonu ,, igbin apinu kan,,ewe ajeobale tutu,,ewe orijin,,epo obo aogun mose aoko sinu Ike funfun aomawe laro laro
09/05/2024
01/05/2024
Happy new month everyone
13/04/2024
Imule ni Ebe awon agba ni eyonu to Rin jina ni EYE KANAKANA KAN. EYE KOWE KAN. AOKO SINU APE TUNTUN AOFI EYE OWIWI KAN SI AOFI TAKO TABO EYE EGA LE AODA ATAIJOSI KONGO KAN LE.AOFI ATARE KAN .AOJO AOLO KI AMAFI OTI TABI OGI GBIGBONA LO
07/04/2024
Happy birthday to you my daughter long life and prosperity
06/04/2024
Oso eyonu aye
Ori ewure ati ese re mererin pelu okan e aoko sinu isasun tuntun Aofi eye kowe kan le aoko isu gbegbe 3,,eru awonka Siri 3,, gbogbo owo currency ti oba wuwa aokole Aofi atare kan le odi jijo aolo aoro sinu sere tabi iGO funfun aomafi oti tabi eko lo laro laro
7036491297
Emiola ismaila
Opay
Fans please support us with any amount o🙏🙏🙏
Asina
Gbogbo wa lamo bi asiko yi seri ki olodumare fi igba rowa Lorun
Aolara bread bite more tabi bread tobani okiki Aofi owo hand bu ninu Aofi 1000 si Aofi Ori oka kan ati eye kowe kan SI ninu Aoki ewe ola mo ninu aowa da peak milk kan SI Aofi atare kan SI aoko ewe sawerepepe ati ewe aje bo aojopo aolo aomafi oti tabi eko lo laro laro
Ebe awon agba. Akuko adire asa totobi kan aopa sinu ape aoge obi gidi kan SI 201,,orogbo 201,,eyo atare 201,,eye kowe kan,,aoko epo obo,, epo igila,,ewe ajeobale tutu,,ewe orijin,,ewe alupaida bo aoda epo pupa iGO kan le Lori aojopo aolo aomafi eko tutu tabi oti lo lalale
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Moniya
Oyo
